UTME past questions
Yoruba / 2012 / 10
UTME Objective

II
Elédùà dëja sínú ibú,
Çja þ gbenú omi,
Çja ò bórí inú wíjö.
Adániwáyé dëranko síjù,
Igbó ni wôn gbé þ jê
Çranko ò sì jiyàn
Béèyàn ò bá gba kádàrá,
Yööyö ní í kéèyàn sí.
Ohun a bá ní, ká jë ó máa tó wa.
Òkèlè àbùjù ní í mú ni í pòfóló.
Ipò tá a bá wà,
Ká jë ó të wa lörùn gëë.
Ohun gbogbo fúngbà díê ni.
Bó ò tí ì rówó kölé,
Tó jáwõsùn lò þ sùn,
ße béèyàn ló þ sun götà.
Bó ÿaÿô méjì péré lo ni,
Rántí çni tó þ wàkísà.
Ëda tí ò gba kádàrá,
Dandan ni kó kánjú j'Olúwa lô
Wön le tipa èyí d'ôlöÿà tó þ dánà.
Bówó lo ní, tówó õhún ò tó nýkan,
Kódà bó o köle, tílé õhún ò põ,
Ôÿö lo bá ní ti ò ragaja,
Jë kó të ô lörùn,
Kóhun gbogbo le rõ ö pêsë.
Ipó kan lo wà, tó o rò pókéré jôjô.
Rántí çni tó fë tó ô.
Itëlörùn ló tó,
Ká mú un ló bíi òÿùwôn ìwà.
Ìyà le fini ÿêsín,
Çsín sì lè máyé sú ni,
Çni ayé bá sú, won kì í gbádùn,
Láyé ti mo wá
N ò ní dúpë túláàsì.


Nínú ewì yìí, Yööyö túmõ sí
A
wàhálÃÂ
B
ìgbéga
C
ìdùnnú
D
àìnítêëlörùn.
Answer:A
Practice more with TestDriller

To see detailed solution to this question and thousands of other questions offline, download TestDriller UTME. Practice rigorously for UTME, learn from video and text materials, enjoy educational games, summary of JAMB literature books, compete with your peers, win prizes and more.

Get TestDriller