UTME past questions
Yoruba / 2012 / 1
UTME Objective

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn
àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
I
Àjàyí wòkè, ó tún wolê, omi bö lójú rê. Òun yìí kan ÿáá
lójoojúmö bí çkún apôkô jç. A kò kúkú rí Àjàyí bá wí fún çkún
àsunrìn. Ôrõ Àdùkë gbèrò, ojoojúmö ló máa þ kó ôkô rê síta bí ômô
ôjö mëjô. Wön ti di sinnimá àdúgbò. Èyí ló fa àròkan àti ìkáríbônú
bí çbôra fún Àjàyí. Ojú tí yóò bá ni kalë kì í tàárõ ÿepin. Nítorí pé
ômô kò kúkú sí láàrín wôn lëyìn ôdún mëta tí wön ti fëra wôn
níÿu lökà, Àjàyí pinnu pé ìyàwó òun yóò lô.
Ohun tí ó þ dá kún wàhálà láàárín wôn ni pé ôjököjö tí Àÿàbí, ìyá
ôkô rê bá ti bè wön wò letí Àdùkë máa þ gbö kòbákùngbé õrõ.
Ômôlèrè, ìyá Àdùkë pàápàá, máa þ sunkún lójoojúmö pé òun fë
fêyìn òun gbé ômôômô àköbí òun põn kí òun tó kú. Àdùkë
ÿakitiyan pé kí àwôn lô fún àyêwò ÿùgbön Àjàyí fàáké körí pé ìran
òun kan kò yàgàn ri; Àdùkë ni kí ó lô yçra rê wò.
Gbogbo ômôbìnrin mëfà tí wön bí têlé Àdùkë ní wön þ
ÿabiyamô. Bí õrõ ti Àdùkë ÿe wá rí yìí kò yé e. Àjàyí kò sì ÿe tàn
láti bá a ÿaájò. Ìdí nìyí tí Àdùkë fi fônmú pé bi kò bá gbà lërö, yóò
gbà ní èle. ßùgbön àìfêlê ké ìbòsí Àdùkë kò jë kí ìbòsí rê ÿe é jó.
Lëyìn õpõ atótónu, tôkôtayà ÿàyêwò ní ilé ìwòsàn ìjôba. Orí Àjàyí
ni aje õrõ náà ÿí mö. Àÿé ó ti ní àrùn gbajúmõ nígbà èwe rê tí kò
mójú tó o bí ó ÿe yç.


Ohun tí ó þ fa ìjà láàárín Àjàyi àti Àdùkë ni
A
àìsífêë
B
àìsömô
C
ìgbóná ara
D
àìfêlê kébòsí.
Answer:B
Practice more with TestDriller

To see detailed solution to this question and thousands of other questions offline, download TestDriller UTME. Practice rigorously for UTME, learn from video and text materials, enjoy educational games, summary of JAMB literature books, compete with your peers, win prizes and more.

Get TestDriller