UTME past questions
Yoruba / 2011 / 36
UTME Objective

Ìwé Àròfọ̀ Ọ̀pádọ̀tun ni ìbéèrè 35 -37 dá lé


Nínú ewì Òkè 'Bàdàn, ìdí tí àwọn Ìbàdàn fi ń fẹ́ra wọ́n ni pé
A
àwọn èèyàn ò fẹ́ fẹ́ eléégún
B
awọ̀n aládùúgbò kọ̀ láti fọmọ fún wọn
C
òrìṣà òkè pàṣẹ fún wọn láti máa ṣe bẹ́ẹ̀
D
wọn ṣe ohun èèwọ̀ awo.
Answer:B
Practice more with TestDriller

To see detailed solution to this question and thousands of other questions offline, download TestDriller UTME. Practice rigorously for UTME, learn from video and text materials, enjoy educational games, summary of JAMB literature books, compete with your peers, win prizes and more.

Get TestDriller