UTME past questions
Yoruba / 2009 / 5
UTME Objective

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn
àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
I
Bàbá Wálé jókòó sórí àga þlá kan nínú pálõ rê, ó þ ronú lórí õrõ
tí ìyàwó rê ÿêÿê bá a sô tán. Ôdún kçta nìyí tí iÿë ti bö löwö bàbá
Wálé tí ó jë pé ìyàwó rê Àjíkë ni ó þ gbö bùkátà ilé wôn. Eyín
jçranjçran wôn ti wá di eyín jeegunjeegun. Àwôn tí wön ti jë
alotòní-má-lo-tàná ti wá di çni tí ó þ fi aÿô lç aÿô lójú. Ìyá Wálé sô
fún ôkô rê pé tí kò bá wá wõrõkõ fi ÿe àdá, òun yóò fi Wálé sílè
fún bàbá rë, òun yóò sì gba ilé baba òun lô. Ìdí ni pé awô kò fë ká
ojú ìlù mö, ebi ayé ti þ ránÿë sí ebi õrun.
Bàbá Wálé kò bèÿù-bêgbà, ó gba ilé õrë rè Adánláwõ lo. Ó kálàyé
balè, Adánláwò ÿèlérí láti ran õrë rë löwö, ÿé ojú ló þ rójú ÿàánú.
Adánláwõ mú bàbá Wále lô sí ilé aláwo lati wo ibi tí ìÿòro bàbá Wálé
ti wá. Arígbábuwó bàbá onífá gbé õpêlê ÿánlê. Ó ki ifá sótùn-un, ó
kì í sósì, ó ní kí bàbá Wálé bá ifá ni gbólóhùn, ó sì ÿe bëê.
Àbálôbábõ ilé aláwo ni pé kí bàbá Wálé lô bô eégún ilé àti òòÿà ôjà,
kí ó ba lé rí ojú rere àwôn òbí rê.
Bàbá Wálé kò bá ifá jiyàn, ó ÿe ohun gbogbo tí ó yç kí ó ÿe.
Rírú çbô ní í gbeni, àìru rè nìjàngbòn. Çbô bàbá Wálé dà, ayé wá
bêrê sí ní yç ë. Òwò búlöõkù gígétà tí ó yàn láàyò, ÿe ló þ mówó
wôlé bí çni tí ó ÿëÿó. Iyá Wálé tí ó tí para mö pé òun kò lè bímô
sínú òÿì, tì ó kõ jálê láti lóyún lé Wálé, ka tó ÿëjú pëë, ó ti di ìyá
ìbejì. Ó di kí ó máa paÿô dà bí õgà. Owó wôlé fún bàbà Wálé, bí ó ÿe
þ kôlémölé ni ó þ ralêmölê. Ôkõ ayökëlë rê kò lóýkà, bêë ni ôkõ tí
ó fi þ kó búlöõkù fún àwôn oníbàárà rê kò níye. Bàbá Wálé di ìlúmõ-
ön-ká, çsêgìrì nílé bàbà Wálé. ße òÿì níí jë ta ni mõ ö rí, owó ní
í jë mo bá ô tan.


ßëÿó túmõ sí
A
bá oÿó mulè
B
ÿë oÿó lësê
C
ÿe oògùn owó
D
ÿe òwò oÿó.
Answer:C
Practice more with TestDriller

To see detailed solution to this question and thousands of other questions offline, download TestDriller UTME. Practice rigorously for UTME, learn from video and text materials, enjoy educational games, summary of JAMB literature books, compete with your peers, win prizes and more.

Get TestDriller