UTME past questions
Yoruba / 2009 / 10
UTME Objective

II
Àìgböràn leku ÿe tó fi dénú ibú,
Àìgböràn leja ÿe tó fi dénu õdàn,
Àìgböràn lõyêlë ÿe tó fi dé kòtò,
Àìgböràn êdá põ lápõ jù.
Eku dénú ibu, eku kú,
Çja dénú õdàn, ó dèrò õrun,
Ôyêlê dé kòtó, ó rèwàlê àÿà.
Ôdö ìwòyí kõmõràn òbí,
Ìmõràn olùkö dàkõti.
Êyìn etí ni tilé Olúwa þ bö sí
Ìmõràn tólùkö fìrírí ÿàjô,
Dòtúbàýtë lójù èwe ìwòyí.
Ìmõràn àgbà kó jô pêlú ìrírí,
Dàÿàdànù òkúta òde baálê.
Ewe ìwòyí a ni,
Bó ti wuni làá lògbà çni.
Èwe ìwòyí tiiri ìpàkö.
Wön nígbà lonígbàá lò,
Ç jë n lògbà tèmi.
Êwù ìgbôràn ti bö sônù lörùn wôn,
Êwù àìgbôràn ló kù lörùn.
Bëê ká wí fúnni ká gbö,
Ká sõrõ fúnni ká gbà,
Níí máyé yçni.
Ewúrë tí ò fë forí gba póþpó,
Àguntàn tí ò fë fêyìn gba kùmõ,
Kó mö ÿàìgbôràn sólówó ê.
Ômô tó kôtí ikún
Ìka àbámõ níí kì bônu
Ìgbà òkétè bá bórù tán,
Irú wôn a sunkún sínú,
Wôn a tún ÿàsun-óde.
Wôn a wò sùn-ùn-ùn domi pòrò.
Wôn a máa ÿomi lójú bí egbére.


Lójú akéwì yìí, àtubõtán ìwà tó gbòde ni
A
ìfàsëyìn
B
oríire
C
àbámõ
D
ìlôsíwájú
Answer:C
Practice more with TestDriller

To see detailed solution to this question and thousands of other questions offline, download TestDriller UTME. Practice rigorously for UTME, learn from video and text materials, enjoy educational games, summary of JAMB literature books, compete with your peers, win prizes and more.

Get TestDriller