Yoruba
/
2008
/
3
UTME
Objective
Ka àwôn àyôkàìsàlê yìÃÂ, Kào sì dáhùn
àwôn ìbéèrè tàó têlé wôn.
I
Olújôkë jë akëkõö ni ilé-êkö girama kan nàìlú ÃÂpë. Lará, Baölá àti
ÃÂyábõ jë õrëminú rê. Nàìbêrê Olújôkë þ se ômô jëjë, kì àkôjá ayé rê.
Kò pë, kò jìnnà, lômô bá di àgùntàn tàó bá ajá rìn tàþ jç ìgbë. Lará
àti Bölá ni gbogbo ilé-êkö mõ pêlú ìrìn àrè, kàwön tó bojú wò,
ÃÂyábõ ti di alábàárìn wôn. Kàyéfì, ômô tàò le rúnta kúnná yçn! Ló
gba çnu olùkö àti àwôn akëkõö.
AlàgbàBölömôpë tààÿe olùkö àgbàilé-êkö náàa máa pàrôwàsÃÂ
àwôn akëkõö rê nÃÂgbàgbogbo, ni õpõ ìgbàa tún rô àwôn olùkö láti
máa fi õrõ ÃÂlörun bö àwôn ômô náàyó. ÃÂùgbön bàa gún iyán nÃÂnú
ewé tàa ro ôkànÃÂnú eèpo-êpà, çni máa yó á kúkú yó ni õrõ õhún
dà. KàJôkë tó gbêyàni olùkö àgbàti fàá lé olùkö àÿààti ìÿe löwö
láti máa bójú tó o.
ÃÂwê, nÃÂgbàtàõrõ ômô náàkò yé olùkö àgbàmö, ni ó bá kõwè sÃÂ
õgbëni àti ìyáàfin Agbájé tàwön þ ÿe òbàJôkë láti fi õrõ ômô wôn
tó wôn létÃÂ. ÃÂmö àtijç, àtimu kò fi àyè sÃÂlè ni ohun tàwôn þ wÃÂ,
wön ti gbàgbé pé bi ìdàbá bàjë tónÃÂdìànÃÂàdà. ÃÂyìn-ò-rçyìn, Jôkë
àti àwôn çmêwàrê gbé jonbo nÃÂbi ojú-mi-làtàwôn þ bá kiri nÃÂbi tÃÂ
àwôn tòkunbõ kán pe àpèjç.
NÃÂlé ìgbafë tàwön fi ìpè sàni àwôn olófòófó `ilú ti ta àwôn
agbèföba lólobó pé àwôn õdaràn kan tàwön dìgbòlu ilé ìfowópamö
ìlú ÃÂpë nàôjö dÃÂê sëyìn þ ÿôdún owó nàilé ìgbafë Kúlúbö. Kété tÃÂ
àwôn agbófinró gbö ni wön bá ta möra tàwön sì ya bo ibi àpèjç
náà. Gbogbo çni tàwön bá nàibi ayçyç õhún ni wön fàòfin gbé
wön dé iwájú adájö. Lëyìn õpõ atótónu lënu àwôn agbçjörò tõtùntòsi,
adájö fi êsùn ìpanilëkúnjayé kan àwôn olùpe àpèjê náàpêlú
ìdájö ikú. Ilé-çjö sì fi êsùn ìgbódegbàfún àwôn ôlöÿàkan `awôn õrë
mêrin pêlú êwõn ôdún mökànlélógún àti iÿë àÿekára.
ÃÂsùn tàilè-çjõ fi kan Olùjôkë àti àwôn çmêwàrê ni
Answer:A
Practice more with TestDriller
Get TestDriller
To see detailed solution to this question and thousands of other questions offline, download TestDriller UTME. Practice rigorously for UTME, learn from video and text materials, enjoy educational games, summary of JAMB literature books, compete with your peers, win prizes and more.
