UTME past questions
Yoruba / 2008 / 1
UTME Objective

Ka àwôn àyôkà ìsàlê yìí, Kí o sì dáhùn
àwôn ìbéèrè tí ó têlé wôn.
I
Olújôkë jë akëkõö ni ilé-êkö girama kan ní ìlú Êpë. Lará, Baölá àti
Ìyábõ jë õrëminú rê. Ní ìbêrê Olújôkë þ se ômô jëjë, kì í kôjá ayé rê.
Kò pë, kò jìnnà, lômô bá di àgùntàn tí ó bá ajá rìn tí þ jç ìgbë. Lará
àti Bölá ni gbogbo ilé-êkö mõ pêlú ìrìn àrè, kí wön tó bojú wò,
Ìyábõ ti di alábàárìn wôn. Kàyéfì, ômô tí ò le rúnta kúnná yçn! Ló
gba çnu olùkö àti àwôn akëkõö.
Alàgbà Bölömôpë tí í ÿe olùkö àgbà ilé-êkö náà a máa pàrôwà sí
àwôn akëkõö rê nígbà gbogbo, ni õpõ ìgbà a tún rô àwôn olùkö láti
máa fi õrõ Ôlörun bö àwôn ômô náà yó. ßùgbön bí a gún iyán nínú
ewé tí a ro ôkà nínú eèpo-êpà, çni máa yó á kúkú yó ni õrõ õhún
dà. Kí Jôkë tó gbêyà ni olùkö àgbà ti fàá lé olùkö àÿà àti ìÿe löwö
láti máa bójú tó o.
Êwê, nígbà tí õrõ ômô náà kò yé olùkö àgbà mö, ni ó bá kõwè sí
õgbëni àti ìyáàfin Agbájé tí wön þ ÿe òbí Jôkë láti fi õrõ ômô wôn
tó wôn létí. Àmö àtijç, àtimu kò fi àyè sílè ni ohun tí wôn þ wí,
wön ti gbàgbé pé bi ìdí bá bà jë tónídìí níí dà. Êyìn-ò-rçyìn, Jôkë
àti àwôn çmêwà rê gbé jonbo níbi ojú-mi-là tí wôn þ bá kiri níbi tí
àwôn tòkunbõ kán pe àpèjç.
Nílé ìgbafë tí wön fi ìpè sí ni àwôn olófòófó `ilú ti ta àwôn
agbèföba lólobó pé àwôn õdaràn kan tí wön dìgbòlu ilé ìfowópamö
ìlú Êpë ní ôjö díê sëyìn þ ÿôdún owó ní ilé ìgbafë Kúlúbö. Kété tí
àwôn agbófinró gbö ni wön bá ta möra tí wön sì ya bo ibi àpèjç
náà. Gbogbo çni tí wön bá ní ibi ayçyç õhún ni wön fí òfin gbé
wön dé iwájú adájö. Lëyìn õpõ atótónu lënu àwôn agbçjörò tõtùntòsi,
adájö fi êsùn ìpanilëkúnjayé kan àwôn olùpe àpèjê náà pêlú
ìdájö ikú. Ilé-çjö sì fi êsùn ìgbódegbà fún àwôn ôlöÿà kan `awôn õrë
mêrin pêlú êwõn ôdún mökànlélógún àti iÿë àÿekára.


Àwôn òbí Olújôkë dágunlá ìpè alàgbà Bölömôpé nítorí
A
iÿë
B
àìráyè
C
àìlówó
D
ìròjú.
Answer:A
Practice more with TestDriller

To see detailed solution to this question and thousands of other questions offline, download TestDriller UTME. Practice rigorously for UTME, learn from video and text materials, enjoy educational games, summary of JAMB literature books, compete with your peers, win prizes and more.

Get TestDriller